Abdelmadjid Tebboune
Ìrísí
Abdelmadjid Tebboune عبد المجيد تبون | |
---|---|
Abdelmadjid Tebboune in 2019 | |
8th President of Algeria | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
�� gun orí àga 19 December 2019 | |
Alákóso Àgbà | Sabri Boukadoum (Acting) Abdelaziz Djerad |
Asíwájú | Abdelaziz Bouteflika |
16th Prime Minister of Algeria | |
In office 25 May 2017 – 15 August 2017 | |
Ààrẹ | Abdelaziz Bouteflika |
Asíwájú | Abdelmalek Sellal |
Arọ́pò | Ahmed Ouyahia |
Minister of Defence | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 19 December 2019 | |
Asíwájú | Ahmed Gaid Salah (as Deputy Minister of Defense) Abdelaziz Bouteflika |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 17 Oṣù Kọkànlá 1945 Mécheria, Algeria |
Abdelmadjid Tebboune (Lárúbáwá: عبد المجيد تبون; ọjọ́ìbí 17 November 1945) ni olóṣèlú ará Algeria tó jẹ́ lọ́wọ́lọ́wọ́ pé òhun ni Ààrẹ ilẹ̀ Algeria láti December 2019. Ó rọ́pò Ààrẹ Abdelaziz Bouteflika àti Arọ́pò Olórí Orílẹ̀-èdè tẹ́lẹ̀ Abdelkader Bensalah. Tẹ́ltẹ́lẹ̀, òhun ló jẹ́ Alákósò Àgbà ilẹ̀ Algeria láti May 2017 di August 2017. Bákannáà, ó tún jẹ́ tẹ́lẹ̀ Alákóso Ètò Ilé láti 2001 di 2002 fún ọdún kan àti ní ẹ̀kan si láti 2012 di 2017 fún ọdún 5.[1]
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Lamlili, Nadia (2017-05-25). "Premier ministre d'Abdelaziz Bouteflika ?" (in fr). Jeune Afrique. Archived from the original on November 2, 2019. https://web.archive.org/web/20191102204034/https://www.jeuneafrique.com/442030/politique/algerie-abdelmadjid-tebboune-nouveau-premier-ministre-dabdelaziz-bouteflika/. Retrieved November 2, 2019.