Èkó
- Èkó wa ni ipoidojuko 6°27′09″N 3°24′49″E / 6.4524°N 3.4136°ECoordinates: 6°27′09″N 3°24′49″E / 6.4524°N 3.4136°E
Lagos Èkó | |||
---|---|---|---|
| |||
Map of Lagos Metropolis | |||
Country | Nigeria | ||
State | Lagos State | ||
LGA | Lagos Island | ||
Area | |||
• Urban | 999.6 km2 (385.9 sq mi) | ||
Population (2006 census, preliminary) | |||
• Density | 7,941/km2 (20,569.9/sq mi) | ||
• Urban | 7,937,932 | ||
Time zone | UTC+1 (CET) | ||
Website | http://www.lagosstate.gov.ng/ |
Èkó (tàbí Lagos ní èdè Gẹ̀ẹ́sì /ˈleɪɡɒs/, US also /ˈlɑːɡoʊs/;[3] Yorùbá: Èkó) ni ìlú tó ní èrò tó pọ̀ jùlọ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti ní gbogbo ilẹ̀ Áfríkà.[4][5] Èkó jẹ́ ilé-ajé pàtàkì ní gbogbo Áfríkà àti oríta okòwò ní Ìpínlẹ̀ Èkó. Èkó gẹ́gẹ́bí ìlú-nínlá ni ó ní GDP kẹrin tó pọ̀ jùlọ ní Áfríkà,[6][7] ibẹ̀ sì ni èbúté ọkọ̀-ojúomi tó tóbi jùlọ àti tó láápọn jùlọ ní ilẹ̀ Áfríkà.[8][9][10] Èkó ni ìkan láàrin àwọn ìlú tí ó ń ní ìgbèdàgbà kíákíá jùlọ ní àgbáyé.[18]
Èkó ní orúkọ tí àwọn Yorùbá ń pè ìlú erékùsù tí ó ti di olú ìlú àti ibùjókòó ìjoba gbogbo-gbòò fún ilè Nàìjíríà ní ojó òní. Ìlú Yorùbá ni, ṣùgbọ́n orúkọ tí àwọn ènìyàn àgbáyé fi ń pè é ni èyí ti àwọn Òyìnbó Potogi tí ó kọ́ bẹ etíkun ilẹ̀ Yorùbá wò fún un. Orúkọ náà ni “Lagos”, èyí tí ìtumọ̀ rẹ̀ jásí “adágún” tàbí “ọ̀sà”, nítorí pé ọ̀sà ni ó yí ìlú náà ká...
Àwọn Ẹ̀yà Yorùbá ti Àwórì ni ó kọ́kọ́ tẹ̀dó si agbègbè Ìlú Èkó, lábé ìṣàkóso àti Ìtọ̀nà olórí wọn, Ọlọ́fin, àwọn Àwórì kọ́kọ́ tẹ̀dó sí erékùsù Ìddó, Lẹ́yìn ìgbà náà ni wọ́n bẹ̀rẹ̀ si ní wọnú àwọn agbègbè yókù Èkó láti tẹ̀dó. Ní séńtúrì karùndínlógún {15th Century}, Ìlú Èkó, bọ́ sí abẹ́ ìṣàkóso Ìjọba Benin. Ìgbà náà ni àwọn Ológun Ìlú náà sọ agbègbè ìlú náà ní Èkó, eléyìí, tí ó túmò sí [Ibi tí àwọn Ológun tí ń simi} Ní èdè Edo/Benin. Gbogbo eléyìí ṣẹlẹ̀ lábẹ́ olórí àwọn Benin ní ìgbà náà Ọba Ọ̀rọ̀gbà. Léyìn tí èyí ṣẹlẹ̀, ni Ìjọba Benin fi Baálẹ̀ jẹ́ oyè, láti máà M'ójútó/Ṣe Àkóso, àti Gbígba Ìṣákọ́lè {Tribute} ìlú náà bíi agbègbè lábé-fé Ìjọba ńlá ti Benin. Ọba Yorùbá àkọ́kọ́ tí ó jẹ ní Ìlú Èkó ni Ọba Aṣípa. Ní ọdun-ún 1472, àwọn Òyìnbó Pọ́tókì{Portuguese} dé sí ilẹ̀ Èkó, àwọn Pọ́tókì náà ní Òyìnbó àkọ́kọ́ , tí ó máa dé Ilẹ̀-Èkó Erékùsù láti Orílè-ẹ̀dẹ̀ Europe ní ìgbà náà.
Àwòrán
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Summing the 16 LGAs making up Metropolitan Lagos (Agége, Ajéròmí-Ìfélódùn, Àlímòshọ́, Àmùwó-Ọ̀dọ̀fin, Àpápá, Etí-Ọ̀sà, Ìfàkò-Ìjàìyè, Ìkejà, Kòsòfẹ́, Lagos Island, Lagos Mainland, Mushin, Ọ̀jọ́, Oshòdì-Ìsolò, Shómólú, Surulérè) as per:
The Nigeria Congress. "Administrative Levels - Lagos State". Archived from the original on 2004-03-12. Retrieved 2007-06-29. - ↑ Summing the 16 LGAs making up Metropolitan Lagos (Agége, Ajéròmí-Ìfélódùn, Àlímòshọ́, Àmùwó-Ọ̀dọ̀fin, Àpápá, Etí-Ọ̀sà, Ìfàkò-Ìjàìyè, Ìkejà, Kòsòfẹ́, Lagos Island, Lagos Mainland, Mushin, Ojo, Oshodi-Isolo, Shomolu, Surulere) as per:
Federal Republic of Nigeria Official Gazette (15 May 2007). "Legal Notice on Publication of the Details of the Breakdown of the National and State Provisional Totals 2006 Census" (PDF). Archived from the original (PDF) on 2007-07-04. Retrieved 2007-06-29. - ↑ Àdàkọ:Cite EPD
- ↑ "What Makes Lagos a Model City". New York Times. 7 January 2014. https://www.nytimes.com/2014/01/08/opinion/what-makes-lagos-a-model-city.html?_r=0. Retrieved 16 March 2015.
- ↑ John Campbell (10 July 2012). "This Is Africa's New Biggest City: Lagos, Nigeria, Population 21 Million". The Atlantic (Washington DC). https://www.theatlantic.com/international/archive/2012/07/this-is-africas-new-biggest-city-lagos-nigeria-population-25-million/259611/. Retrieved 23 September 2012.
- ↑ "These cities are the hubs of Africa’s economic boom". Big Think (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-10-04. Retrieved 2019-04-23.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedmetropolitan Lagos
- ↑ "Africa's biggest shipping ports". Businesstech. 8 March 2015. Retrieved 26 October 2015.
- ↑ Brian Rajewski (1998). Africa, Volume 1 of Cities of the World: a compilation of current information on cultural, geographical, and political conditions in the countries and cities of six continents, based on the Department of State's "post reports". Gale Research International, Limited. ISBN 978-0-810-3769-22. https://books.google.com/books?id=E-VwMKQlGjIC.
- ↑ Loretta Lees; Hyun Bang Shin; Ernesto López Morales (2015). Global Gentrifications: Uneven Development and Displacement. Policy Press. p. 315. ISBN 978-1-447-3134-89. https://books.google.com/books?id=Lzt7BgAAQBAJ&pg=PA315&dq=.
- ↑ African Cities Driving the NEPAD Initiative. 2006. p. 202. ISBN 978-9-211318159. https://books.google.com/books?id=tk5TP7bsXnkC&pg=PA202&dq=.
- ↑ John Hartley; Jason Potts; Terry Flew; Stuart Cunningham; Michael Keane; John Banks (2012). Key Concepts in Creative Industries. SAGE. p. 47. ISBN 978-1-446-2028-90. https://books.google.com/books?id=sMnj88kYVmcC&pg=PT60&dq=.
- ↑ Helmut K Anheier; Yudhishthir Raj Isar (2012). Cultures and Globalization: Cities, Cultural Policy and Governance. SAGE. p. 118. ISBN 978-1-446-2585-07. https://books.google.com/books?id=wQJb1QpZz_4C&pg=PA118&dq=.
- ↑ Stuart Cunningham (2013). Hidden Innovation: Policy, Industry and the Creative Sector (Creative Economy and Innovation Culture Se Series). Univ. of Queensland Press. p. 163. ISBN 978-0-702-2509-89. https://books.google.com/books?id=oy-de29AtvYC&pg=PA163.
- ↑ Lisa Benton-Short; John Rennie Short (2013). Cities and Nature. Routledge Critical Introductions to Urbanism and the City. p. 7. ISBN 978-1-134252749. https://books.google.com/books?id=rQ_ZLuqZT54C&pg=PA71&dq=.
- ↑ Kerstin Pinther; Larissa Förster; Christian Hanussek (2012). "Afropolis: City Media Art". Jacana Media. p. 18. ISBN 978-1-431-4032-57.
- ↑ Salif Diop; Jean-Paul Barusseau; Cyr Descamps (2014). The Land/Ocean Interactions in the Coastal Zone of West and Central Africa Estuaries of the World. Springer. p. 66. ISBN 978-3-319-0638-81. https://books.google.com/books?id=8JPIAwAAQBAJ&pg=PA66&dq=.
- ↑ Sources: [11][12][13][14][15][16][17]
- J.F. Odunjo (1969), ÌLÚ ÈKÓ ATI ÌJÈBÚ, Isẹ́ Àtúnyèwò ẹ̀kọ́ nipa ọ̀rọ̀ gbígbàsọ Ojú-ìwé 49-54, Èkó Ìjìnlẹ̀ Yorùbá Alawiye, Fún Àwọn Ilé Ẹ̀kó Gíga, Apá Kejì, Longmans of Nigeria.
Ìtọ́kasí Àrè
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Àwọn Ilé ìsimi tówà Leko(Lagos Hotels). Archived 2011-10-01 at the Wayback Machine.
- Pages with non-numeric formatnum arguments
- Pages with reference errors
- CS1 Èdè Gẹ̀ẹ́sì-language sources (en)
- Coordinates on Wikidata
- Pages using infobox settlement with unknown parameters
- Articles containing Yorùbá-language text
- Webarchive template wayback links
- Àwọn ìlú àti abúlé ní Ìpínlẹ̀ Èkó
- Àwọn ìlú àti abúlé ní Nàìjíríà