Jump to content

Ilẹ̀ Ọbalúayé Sọ́ngháì

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Songhai Empire)
Ilé Ìjoba Songhai
Ìjoba

c. 1340–1591
 

Location of Ilé Ìjoba Songhai tabi Orílè Songhai
The Songhai Empire, (ca. 1500)
Capital Gao
Language(s) Songhai
Religion Islam (Èsin Ìmàle)
Government Ije Oba
Sonni; later Askiya
 - 1468-1492 Sunni Ali (first)
 - 1588-1591 Askia Mohammad I (last)
History
 - Orílè Songhai bèrè ní Gao c.1000
 - Songhai gba òmìnira l'ówó Ìjoba Mali pátápátá c. 1340
 - Songhai fi ogun bere si ni fe ibudo won 1460
 - Ìgba ìjoba l'owo Ìdíle Sunni 1493
 - Ìdíle Saadi pa Orílè Songhai run 1591
 - Ifi ìdi Orílè Songhai mule ìjoba Dendi 1592

The Dendi Kingdom ends 1901

Area
 - 1500[1] 1,400,000 km2 (540,543 sq mi)
 - 1550[2] 800,000 km2 (308,882 sq mi)
Currency Cowries
(wura, iyò ati copper ni wón n ná)
Warning: Value specified for "continent" does not comply

Ile Ìjoba Songhai, tàbí Ile Ìjoba Songhay, je ile-ijoba ni iwoorun Afrika ní ìgbàkan rí. [3]Lati ibere orundun 15th titi de opin orundun 16th, Songhai je ikan ninu awon ile ìjoba Afrika tí ò tobi julo ni itan aye. Oruko re wá lati oruko awon eya eniyan to siwaju nibe, eyun awon Songhai. Oluilu re wa ni ilu Gao, nibi ti ile-ijoba Songhai kekere kan ti wà lati orundun 11th. Ibujoko agbara re wa ni koro apa Odo Oya ni orile-ede Niger loni ati Burkina Faso.



Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Hunwick, page xlix
  2. Taagepera, page 497
  3. Cartwright, Mark (2019-03-08). "Songhai Empire". World History Encyclopedia. Retrieved 2023-08-10.