Jump to content

Sofia Kenin

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Sofia Kenin
Kenin at the 2019 French Open
Orílẹ̀-èdèUSA USA
IbùgbéPembroke Pines, Florida, US
Ọjọ́ìbí14 Oṣù Kọkànlá 1998 (1998-11-14) (ọmọ ọdún 26)
Moscow, Russia
Ìga1.70 m (5 ft 7 in)
Ìgbà tódi oníwọ̀fà2017
Ọwọ́ ìgbáyòRight-handed
(two-handed backhand)
Olùkọ́niAlex Kenin
Ẹ̀bùn owóUS$ 5,930,775
Ojúewé Íntánẹ́ẹ̀tìsonyakenin.com
Ẹnìkan
Iye ìdíje205–116 (63.86%)
Iye ife-ẹ̀yẹ5
Ipò rẹ̀ gígajùlọNo. 4 (March 9, 2020)
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́No. 4 (March 9, 2020)
Grand Slam Singles results
Open AustrálíàW (2020)
Open Fránsì4R (2019)
Wimbledon2R (2018, 2019)
Open Amẹ́ríkà3R (2017, 2018, 2019)
Àwọn ìdíje míràn
Ìdíje WTARR (2019)
Ẹniméjì
Iye ìdíje56–45 (55.45%)
Iye ife-ẹ̀yẹ2
Ipò rẹ̀ gígajùlọNo. 32 (March 2, 2020)
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́No. 32 (March 9, 2020)
Grand Slam Doubles results
Open Austrálíà3R (2020)
Open Fránsì2R (2019)
Wimbledon2R (2018)
Open Amẹ́ríkà1R (2018, 2019)
Àwọn Ìdíje Ẹgbẹ́ Agbáyò
Fed CupF (2018)
Last updated on: Àdàkọ:Date.

Sofia Anna Kenin[1] (pẹ̀lú ìnagijẹ Sonya, /ˈsniə ˈkɛnɪn/ SOH-nee-ə-_-KEN;[2] ọjọ́ìbí November 14, 1998) ni agbá tẹ́nìs ará Amẹ́ríkà. Ipò rẹ̀ tógajùlọ láàgbáyé àjọ Women's Tennis Association (WTA) ni No. 4. Kenin gba ife-ẹ̀yẹ Open Australi 2020 nígbà tó borí Garbine Muguruza ní ìparí ìdúje náà, èyì sọ ọ́ di ọ̀dọ́mọdé kékeré jùlọ ará Amẹ́ríkà tó gba ìdíje Grand Slam àwọn ọbìnrin ẹnìkan lẹ́yìn Serena Williams ní 2002.

  1. "Sonya Kenin Biography". Sonya Kenin. Retrieved 6 March 2020. 
  2. "Sofia Kenin, una tenista lista para el profesionalismo". VamosDeportes. 22 December 2014. Retrieved 3 January 2018.