Nọ́mbà àkọ́kọ́
Ninu Ìmọ̀ Ìṣirò nọ́mbà àkọ́kọ́ (prime numbers) ni a si àwọn nomba adabaye (natural numbers) tí wọn ní nọmba ádábá méjí péreé tí a lè fí pín wọn dọ́gba, éyí ní nọmbaa 1 atí nọmba ákọkọ fún árá rẹ. Áwọn nọmba ákọkọ pọ tó bẹẹ tó fí jẹ wípé wọn kò lòpin gẹgẹe bí Efklidi ṣé fihàn ní ọdúnn 300 K.J (kia to bi Jesu, K.J). Nọmba ódò 0 ati ọ̀kan 1 kì ṣé nọmba akọkọ.
Bí àwọnon nọmba akọkọ ṣé
ẹètárá wọn wí íi yi : 2, 3, 5, 7, 11, 13, 17, 19, 23, 29, 31, 37, 41, 43, 47, 53, 59, 61, 67, 71, 73, 79, 83, 89, 97, 101, 103, 107, àtí, and 113
Nọmba 2 (íkèji)
í
i
íó
ẹ
Nomba Akoko gege bi baba awon ááoíba ọdabÁ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]ọIpóleùse ẹAbagbo Isesiro la kale pe gbogbo nọ́mbà odidi (integers) apa otun ti won tobi ju 1 lo se ko sile gege bi isodipupo nomba akoko kan tabi jubelo ni ona kan pato. Fun apere a le ko:
Gbogbo Awon Nomba Akoko
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Awon nomba akoko ko ni ye. Eyi ti je fifihan lopolopo ona. Eni akoko to koko fi eyi han ni Efklidi. Bi o se fi han ni yi:
- E je ki a so pe awon nomba akoko to l'opin (finite) kan wa. E je ki a pe awon nomba wonyi ni m. Se isodipupo gbogbo m, ki o si se aropo re pelu okan (nomba Efklidi). Nomba esi ti ri ko se pin pelu ikojopo number akoko kankan t'olopin, nitoripe bi a ba se pin to okan yio seku, be sini okan ko se pin pelu nomba akoko. Nipa bayi, tabi ki o je nomba akoko fun ra ara re tabi ki o se pin pelu nomba akoko miran ti ko si ninu ikojopo to l'opin. Botiwulekaje, a gbudo ni nomba akoko ti yio je m + 1.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |