Nicolas Sarkozy
Nicolas Sarkozy | |
---|---|
Aare ile Fransi | |
In office 16 May 2007 – 15 May 2012 | |
Alákóso Àgbà | François Fillon |
Asíwájú | Jacques Chirac |
Arọ́pò | François Hollande |
Co-Prince of Andorra | |
In office 16 May 2007 – 15 May 2012 Served with Joan Enric Vives Sicília | |
Alákóso Àgbà | Albert Pintat Jaume Bartumeu Pere López Agràs (Acting) Antoni Martí |
Representative | Philippe Massoni Emmanuelle Mignon Christian Frémont |
Asíwájú | Jacques Chirac |
Arọ́pò | François Hollande |
Alakoso Oro Abele ile Fransi | |
In office 31 May 2005 – 26 March 2007 | |
Alákóso Àgbà | Dominique de Villepin |
Asíwájú | Dominique de Villepin |
Arọ́pò | François Baroin |
In office 7 May 2002 – 31 March 2004 | |
Alákóso Àgbà | Jean-Pierre Raffarin |
Asíwájú | Daniel Vaillant |
Arọ́pò | Dominique de Villepin |
Alakoso Okowo, Inawo ati Oro Ile-ise ero ile Fransi | |
In office 31 March 2004 – 28 November 2004 | |
Alákóso Àgbà | Jean-Pierre Raffarin |
Asíwájú | Francis Mer |
Arọ́pò | Hervé Gaymard |
Alakoso Isuna | |
In office 29 March 1993 – 10 May 1995 | |
Alákóso Àgbà | Edouard Balladur |
Asíwájú | Michel Charasse |
Arọ́pò | None |
Baale ilu Neuilly-sur-Seine | |
In office 1983–2002 | |
Asíwájú | Achille Peretti |
Arọ́pò | Louis-Charles Bary |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 28 Oṣù Kínní 1955 Paris, France |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | RR (?–2002) UMP (2002–) |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Marie-Dominique Culioli (div.) Cécilia Ciganer-Albéniz (div.) Carla Bruni |
Àwọn ọmọ | Pierre (by Culioli) Jean (by Culioli) Louis (by Ciganer-Albéniz) |
Residence | Élysée Palace |
Alma mater | University of Paris X: Nanterre |
Occupation | Lawyer |
Signature | |
Website | sarkozy.fr |
Nicolas Sarkozy, Abase Omoba ile Andorra (pronounced [nikɔla saʁkɔzi] (ìrànwọ́·info), oruko abiso Nicolas Paul Stéphane Sarközy de Nagy-Bocsa ni 28 Osu kinni, 1955) ni Aare ile Fransi lati 2007 de 2012 ati nitorire Abase Omoba ile Andorra lati 2007 de 2012. O gun ori aga ni 16 Osu karun, 2007 leyin to bori candidate Ségolène Royal ti Egbe Sosialisti ni ojo 10 seyin.
Igbe aye
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Itan Ebi re
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Sarkozy je ara Fransi aladalu eyan eniyan. Omo Pál István Ernő Sárközy de Nagy-Bócsa,[1] to oloye ara Hungari,[2] ati Andrée Jeanne "Dadu" Mallah (ojoibi 12 Osu kewa, 1925 ni Paris), to je ara Fransi elesin Katolik ati Ju Sefardik lati Ottoman.[3] Won fe ra won ni Saint-François-de-Sales, Paris XVII, ni 8 Osu keji, 1950 won su kora won sile ni 1959.[4]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Schmemann, Serge (15 May 2007). "The New French President's Roots Are Worth Remembering". The New York Times. http://www.nytimes.com/2007/05/15/opinion/15tue4.html?_r=2&th&emc=th&oref=slogin&oref=slogin. Retrieved 28 September 2008.
- ↑ It is the "westernised", or "internationalised", version of his Hungarian name, in which the given name is put first (whereas in Hungarian given names come last), and the French aristocratic particle "de" is used instead of the Hungarian aristocratic ending "-i". This "westernisation" of Hungarian names is frequent, particularly for people with an aristocratic name. Check for example the leader of Hungary from 1920 to 1944, whose Hungarian name is nagybányai Horthy Miklós, but who is known in English as Miklós Horthy de Nagybánya. The French name of Pál Sárközy de Nagy-Bócsa from 1948 is Paul Étienne Arnaud Sarközy de Nagy-Bocsa, where the given name Pál has been translated into Paul in French, and the acute accents on the "a" of Sarközy and the "o" of Bocsa were dropped as these letters never carry an acute accent (accent aigu) in French. The trema on the "o" of Sárközy was kept, probably because French typewriters allow this combination, whereas it is impossible to write "a" or "o" with an acute accent using a French typewriter.
- ↑ "Profile: Nicolas Sarkozy". BBC News. 26 July 2009. http://news.bbc.co.uk/2/hi/europe/3673102.stm. Retrieved 9 March 2010.
- ↑ "Ancestry of Nicolas Sarkozy". William Addams Reitwiesner. Retrieved 9 March 2010.