Mobutu Sese Seko
Ìrísí
Mobutu Sésé Seko | |
---|---|
Aare ile Zaire | |
In office 24 November 1965 – 16 May 1997 | |
Alákóso Àgbà | opolopo |
Asíwájú | Joseph Kasa-Vubu |
Arọ́pò | Laurent-Désiré Kabila |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Lisala, Belgian Congo | 14 Oṣù Kẹ̀wá 1930
Aláìsí | 7 September 1997 Rabat, Morocco | (ọmọ ọdún 66)
Ọmọorílẹ̀-èdè | Congolese |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Popular Movement of the Revolution |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Marie-Antoinette Mobutu (alaisi) Bobi Ladawa |
Mobutu Sésé Seko Nkuku Ngbendu wa Za Banga (14 October 1930– 7 September 1997), to gbajumo gege bi Mobutu tabi Mobutu Sésé Seko (pípè /məˈbuːtuː ˈsɛseɪ ˈsɛkoʊ/), oruko abiso Joseph-Désiré Mobutu, lo di olori orile-ede Zaire (loni gege bi Olominira Toselu ile Kongo) leyin igba to fipagbajoba lowo Joseph Kasavubu.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wikimedia Commons ní àwọn amóunmáwòrán bíbátan mọ́: Mobutu Sese Seko |