Jump to content

Mamman Bello Ali

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Mamman Bello Ali
Senator - Yobe South
In office
May 1999 – May 2007
Governor - Yobe State
In office
29 May 2007 – 27 January 2009
AsíwájúBukar Abba Ibrahim
Arọ́pòIbrahim Geidam
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí1958
AláìsíJanuary 27, 2009

Mamman Bello Ali (1958 – 27 January, 2009) je oloselu omo ile Naijiria ati Gomina Ipinle Yobe lati odun 2007 titi de 27 January, 2009 nigba to di alaisi. Ki o to di Gomina o ti koko je Alagba ni Ile Alagba Ile Igbimo Asofin Naijiria lati 1999. O di alaisi ni 27 January, 2009 nipa aisan Leukemia