Jump to content

Juliana Negedu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Juliana Ojoshogu Negedu (tí wọ́n bí ní 31 July 1979 ní Ìpínlẹ̀ Kaduna) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù alájùsáwọ̀n ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ ọmọ-ẹgbẹ́ Nigeria women's national basketball team, ó sì kópa nínú ìdíje 2004 Summer Olympics, Negedu gba pọ́ìntì mẹ́jọ nínú ayò márùn-ún.[1]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Juliana Ojoshogu NEGEDU Biography, Olympic Medals, Records and Age". Olympics.com. 2023-06-12. Retrieved 2024-04-04.