Jump to content

John Milton

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
John Milton
Portrait of John Milton in National Portrait Gallery, London ca. 1629. Unknown artist (detail)
Ọjọ́ ìbí9 December 1608
Bread Street, Cheapside, London, England
Ọjọ́ aláìsí8 November 1674 (aged 65)
Bunhill, London, England
Resting placeSt Giles-without-Cripplegate
Iṣẹ́Poet, prose polemicist, civil servant
ÈdèEnglish, Latin, French, German, Greek, Hebrew, Italian, Spanish, Aramaic, Syriac
Ọmọ orílẹ̀-èdèEnglish
Alma materChrist's College, University of Cambridge

Signature

John Milton (9 December 1608 – 8 November 1674) je akoewi ara Ilegeesi, agbogunti, omowe, ati osise ijoba fun Kajola Ilegeesi labe Oliver Cromwell. O ko awon iwe re nigba rogbodiyan esin ati oselu, o si gbajumo fun ewi akoni re Paradise Lost.