Frank Lampard
Ìrísí

Frank James Lampard jẹ́ àgbà-ọ̀jẹ̀ agbábọ́ọ̀lù-aláfẹsẹ̀gbá ti orílẹ̀-èdè United Kingdom. Ó ti fi ìgbà kan jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ikọ̀ Chelsea kí wọ́n tó wá yàn-án láìpẹ́ yìí gẹ́gẹ́ bíi Akọ́nimọ̀-ọ́n-gbá fún ikọ̀ Chelsea bákan náà lọ́dún 2019.[1] Gẹ́gẹ́ bíi agbábọ́ọ̀lù, ó jẹ́ ọ̀gbóǹtarìgì agbábọ́ọ̀lù ààringbùngbùn orí pápá lásìkò rẹ̀.[2] A bí Frank Lampard ní ogúnjọ́ oṣù kẹfà ọdún 1978.[3]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Manager profile". Transfermarkt. Retrieved 2019-09-19.
- ↑ S, Aditya M (2011-01-21). "World Football: The Top 10 Midfielders of the Past Decade". Bleacher Report. Retrieved 2019-09-19.
- ↑ "Manager profile". Transfermarkt. Retrieved 2019-09-19.