Cynthia Uwak
Ìrísí
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Cynthia Uwak | ||
Ọjọ́ ìbí | 15 Oṣù Keje 1986 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Nigeria | ||
Ìga | 1.6m | ||
Playing position | Forward (association football)#Striker | ||
Club information | |||
Current club | Åland United | ||
Number | 18 | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
2005 | Kuopion MimmiFutis | ||
2006 | FC United (Finland) | (17) | |
2007 | Falköpings KIK | ||
2008 | FC United (Finland) | ||
2008–2009 | Olympique Lyonnais (ladies) | ||
2009 | Kuopion MimmiFutis | 12 | (18) |
2009–2011 | 1. FC Saarbrücken | 42 | (12) |
2011–2012 | PK-35 Vantaa (women) | 29 | (22) |
2012– | Åland United | 32 | (22) |
National team | |||
2002 | Nigeria women's national under-20 football team | ||
2004– | Nigeria women's national football team | ||
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only and correct as of 21 June 2014. † Appearances (Goals). |
Cynthia Uwak jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 15, óṣu July ni ọdun 1986. Arabinrin naa ṣere lọwọ fun Aland United ni Naisten Liiga, Finland[1][2][3].
Àṣeyọri
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Cynthia gba ami ẹyẹ gẹgẹbi Agbabọọlu lobinrin ilẹ Afirica ni ọdun 2006 ati 2007[4][5].
- Cynthia kopa ninu Cup FIFA awọn obinrin agbaye ni ọdun 2007 ati olympic ọdun 2008[6].
Itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ https://www.eurosport.com/football/cynthia-uwak_prs333885/person.shtml
- ↑ https://fbref.com/en/players/5224f84d/Cynthia-Uwak
- ↑ https://allafrica.com/stories/201605110267.html
- ↑ https://goalballlive.com/african-women-footballer-of-the-year/
- ↑ https://www.allnigeriasoccer.com/read_news.php?nid=21748
- ↑ https://www.fifa.com/tournaments/womens/womensworldcup/china2007/match-center/56318