Jump to content

Curaçao

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Erekusu Ileagbegbe Curaçao
Island Territory of Curaçao

Eilandgebied Curaçao
Teritorio Insular di Kòrsou
Flag of Curaçao
Àsìá
Àmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ Curaçao
Àmì ọ̀pá àṣẹ
Orin ìyìn: Himno di Kòrsou
Location of Curaçao
Olùìlú
àti ìlú tótóbijùlọ
Willemstad
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaDutch, Papiamentu, English and Spanish
ÌjọbaSee Politics of the Netherlands Antilles
• Monarch
King Willem-Alexander of the Netherlands
• Govenor
Lucille George-Wout
Eugene Rhuggenaath
Constitutional monarchy 
Ìtóbi
• Total
444 km2 (171 sq mi)
Alábùgbé
• 2009 census
141,766
• Ìdìmọ́ra
319/km2 (826.2/sq mi) (ranked as part of N. A.)
OwónínáNetherlands Antillean guilder (ANG)
Ibi àkókòUTC-4 (-4)
Ojúọ̀nà ọkọ́right
Àmì tẹlifóònù599
ISO 3166 codeCW
Internet TLD.an
Handelskade in Willemstad, Curaçao

Curaçao (pípè /ˈkjʊərəsaʊ/; Duki: Curaçao, Papiamentu: Kòrsou) je erekusu ni apaguusu Omi-okun Karibeani, nitosi etiomi Venezuela. Erekusu Ileagbegbe Curaçao[1] (Dutch: Eilandgebied Curaçao, Papiamentu: Teritorio Insular di Kòrsou), to lamupo mo erekusu gbangba na ati ereku Klein Curaçao ("Curaçao Kekere"), je ikan ninu awon erekusu ileagbegbe Netherlands Antilles, nipa bayi o je apa kan Ileoba awon Nedalandi. Oluilu re ni Willemstad.

Coordinates: 12°11′N 69°00′W / 12.183°N 69.000°W / 12.183; -69.000


  1. English name used by government of Curaçao and Government of Netherlands Antilles (English is official language of Netherlands Antilles and Island Territory of Curaçao)