Jump to content

Buchi Emecheta

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Buchi Emecheta
Officer of the Order of the British Empire
July21_Buchi_Emecheta
Ọjọ́ìbíFlorence Onyebuchi Emecheta
21 July 1944
Lagos, Nigeria
Aláìsí25 January 2017(2017-01-25) (ọmọ ọdún 72)
London, England
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ẹ̀kọ́
  • Methodist Girls' High School
  • University of London
Iṣẹ́Writer
Notable work
  • In the Ditch (novel) (1972)
  • Second Class Citizen (novel) (1974)
  • The Bride Price (1976)
  • The Slave Girl (novel) (1977)
  • The Joys of Motherhood (1979)
Websitehttp://www.buchiemecheta.co.uk

Buchi Emecheta je olukowe omo ile Naijiria ta bini óṣu July ọdun 1944 to si ku ni ọjọ kàrunlèèlogun, óṣu January ni ọdun 2017. Aràbinrin naa bẹrẹ si ni gbe ilẹ UK lati ọdun 1962 nibi to tin kọ lóri plays, itan ati nipa awọn ọmọde[1][2][3]

Ígbèsi Àyè Àràbinrin naa

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Buchi Emecheta ni à bini óṣu july, ọdun 1944 si ilú Eko fun Alice Okwuekwuhe Emecheta ati Jeremy Nwabudinke. Awọn óbi arabinrin naa wa lati Umuezeokolo. Ibusa ni Ipinlẹ Delta. Baba olukọwè naa jẹ óṣiṣẹ ti Railway ati Amọ ikan[4][5]

Arabinrin naa wa lara ọmọ ẹgbẹ ti ilè british secretary advisory council race ni ọdun 1979[6]

Ni ọdun 1960, Arabinrin naa fẹ Sylvester Onwordi to si bi ọmọ ọkunrin ati óbinrin. Onwordi lọsi ilè iwè ni ilú london ti Emecheta ati awọn ọmọ rẹ si darapọ mọ ni ọdun 1962. Larin ọdun mẹfa, Emecheta bi ọmọ mààrun; ọmọ óbinrin mẹta ati ọmọ ọkunrin meji. Igbèyawó arabinrin naa koro to si kun fun jagidigan eleyi lo mu kuro lọdọ ọkọ rẹ to si awọn ọmọ rẹ dani.[7][8][9]

Nitóri ipó tiwọn fi awọn óbinrin sini awujọ, aburó Buchi ló kọkọ lọsi ilè iwè ṣugbọn lẹyin arọwa fub awọn óbi buchi ni ó to lọsi ilè iwè missionary ti awọn óbinrin lẹyin ọdun kan ni Emecheta gba ẹkọ ọfẹ lati lọsi ilè iwè methodist ti awọn óbinrin ni Yaba. Buchi gba B.Sc. lori imọ sociology ni ọdun 1972 ni ilè iwè giga ti london lẹyin naa lo gba PhD ni ilè iwè giga naa ni 1991.[6][10][11][12]

Ami Ẹyẹ ati Idanilọla

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Arabinrin naa gba idanilọla lóri literature rẹ to si gba ẹbun ti Jock Campbell ni ọdun 1978 fun iwè rẹ ti akọlè naa jẹ "Ẹrú Óbinrin".[13] Buchi wa lori magazine ti Granta to da lóri awọn ólukọwè ọdọ to darajulọ ti ọdun 1983.[14]

Buchi gba doctorate ta fi da lọla lori literature lati ọdọ ilè iwè giga ti Farleigh Dickinson ni ọdun 1992[15].

Ni óṣu September, ọdun 2004 Buchi wa ninu Awóran ti "A Great Day in London" to da lóri awọn ólúkọwẹ alawọ dudu ati funfun to kopa ninu itẹsiwaju literature ti ilẹ british[16].

Ni ọdun 2005, Buchi ni a da lọlà OBE lóri iṣẹ ribi ribi tó ṣè lori literature.

  1. "Buchi Emecheta - Biography, Books, & Facts". Encyclopedia Britannica. 1998-07-20. Retrieved 2022-11-27. 
  2. Gale, C.L. (2016). A Study Guide for Buchi Emecheta's "The Joys of Motherhood". Novels for Students. Gale, Cengage Learning. ISBN 978-1-4103-5026-8. https://books.google.com.ng/books?id=i5WpDAAAQBAJ. Retrieved 2022-11-27. 
  3. Onwordi, Sylvester (2017-01-31). "Remembering my mother Buchi Emecheta, 1944-2017". New Statesman. Retrieved 2022-11-27. 
  4. Ross, R.; Ross, R.L. (1999). Colonial and Postcolonial Fiction: An Anthology. Children's literature and culture. Garland Pub.. p. 319. ISBN 978-0-8153-1431-8. https://books.google.com.ng/books?id=W1tZoZ-GcTIC&pg=PA319. Retrieved 2022-11-27. 
  5. Ray, E.M.K. (2007). The Atlantic Companion to Literature in English. Atlantic Publishers & Distributors (P) Limited. p. 164. ISBN 978-81-269-0832-5. https://books.google.com.ng/books?id=A_YatfLrgnMC&pg=PA164. Retrieved 2022-11-27. 
  6. 6.0 6.1 Sleeman, E. (2001). The International Who's Who of Women 2002. International Who's Who of Women. Taylor & Francis Group. p. 161. ISBN 978-1-85743-122-3. https://books.google.com.ng/books?id=6J8xDWDqOkEC&pg=PA161. Retrieved 2022-11-27. 
  7. "Culture stars who died in 2017: from Doreen Keogh to Bruce Forsyth". The Telegraph. 2017-01-23. Retrieved 2022-11-27. 
  8. Gale, C.L. (2016). A Study Guide for Buchi Emecheta's "The Bride Price". Novels for Students. Gale, Cengage Learning. p. 6. ISBN 978-1-4103-4203-4. https://books.google.com.ng/books?id=7EiVDAAAQBAJ&pg=PT6. Retrieved 2022-11-27. 
  9. Henry, O. (2022-06-07). "Buchi Emecheta Emecheta, Buchi (Contemporary Literary Criticism) - Essay". eNotes. 
  10. Kean, Danuta (2017-01-26). "Buchi Emecheta, pioneering Nigerian novelist, dies aged 72". the Guardian. Retrieved 2022-11-27. 
  11. "LOUD WHISPERS: The First Class Citizen (Buchi Emecheta 1944-2017)". AboveWhispers. 2017-02-18. Retrieved 2022-11-27. 
  12. Watson, T. (2004). Contemporary Authors. Contemporary Authors New Revision. Gale. ISBN 978-0-7876-6718-4. https://books.google.com.ng/books?id=1GuvNSoG2WIC. Retrieved 2022-11-27. 
  13. "Buchi Emecheta". Encyclopedia.com. 2018-05-23. Retrieved 2022-11-27. 
  14. "Head Above Water". Granta. 1983-03-01. Retrieved 2022-11-27. 
  15. Jagne, S.F.; Parekh, P.N. (2012). Postcolonial African Writers: A Bio-bibliographical Critical Sourcebook. SIOP Organizational Frontiers. Taylor & Francis. p. 149. ISBN 978-1-136-59397-0. https://books.google.com.ng/books?id=3iibMu0Qjs8C&pg=PA149. Retrieved 2022-11-27. 
  16. Levy, Andrea (2004-09-18). "Made in Britain". the Guardian. Retrieved 2022-11-27.