Adelard ará Bath
Adelard ara Bath tabi Adelard de Bada (Latin: Adelardus Bathensis) (c. 1080 – c. 1152) je omowe ara Ilegeesi ni orundun 12th scholar. O gbajumo fun ise akoko re ati fun iyipadaede awon iwe sayensi pataki ni iworawo, itorawo, imoye ati mathimatiki latede Griki ati Larubawa si ede Latin lati atejade Larubawa, latibe ni won ti mu won wa si Apaiwoorun Europe. O keko ni Tours, o soluko fun gba die ni Laon, layin re lo rinajo lo si Apaguusu Italia, Syracuse ni Sicily, ati Antioch ni Asia Kekere. O budo si Bath ni Ilegeesi ni odun 1122.[2] O je eni igba kanna pelu William ara Conches, o si je eni to mo sode eye to si mo fere fan.[3]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Russell, Bertrand. A History of Western Philosophy. p. 212.
- ↑ There is some uncertainty on the details of his career; see Burnett (1987) and Burnett (1999).
- ↑ Hannam, James. God's Philosophers. pp66-69.
Awon ijapo sode
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ADELHARD[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- Àdàkọ:MacTutor Biography
- Adelhard (Adelard) of Bath - Give and take reason
- Adelard of Bath Archived 2011-09-28 at the Wayback Machine. Timeline from the Bath Royal Literary and Scientific Institution
- Extract from Adelard's "Very Difficult Natural Questions" Archived 2007-10-30 at the Wayback Machine.