Ludwig van Beethoven
Ìrísí


Ludwig van Beethoven (pípè /ˈluːdvɪɡ vɑːn ˈbeɪtoʊvən/ (U.S.)tabi /ˈlʊdvɪɡ væn ˈbeɪt.hoʊvən/ (UK); Jẹ́mánì: [ˈluːtvɪç fan ˈbeːt.hoːfn̩] ( listen); iribomi ni 17 December 1770[1] – 26 March 1827) je alakopo orin ati oniduuru ara ile Jemani. Ohun ni eni pataki ju nigba iyipada larin igba orin Klasika ati Romantik ninu orin klasika Europe, be sini o je alakopo orin togbajulo ati tonipajulo.
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |