Tunji Braithwaite
Ìrísí
Lóóyà ni Dr Túnjí Braithwaite olósèlú sì ni Wón bí Dr Braithwaite ní ojó kerìndínlógún osù késàn-án odún 1943. Òun ni ó dá Nigeria Advanced Party (NAP) tí wón ti paré sílè. Ó gbé àpótí fún ipò Ààre ilè Nàìjíríà lábé egbé Grassroots Democratic Advanced Movement (DAM).