Robert Menzies
Ìrísí
Omo ile Australia ni Menzies. A bi i ni 1894. O je olootu ijoba ile Australia fun odun mokandinlogun. Ilu Jepart ni won ti bi i ni Victoria. O gba oye ninu ofin ni University Melborne. Ni aarin 1928 si 1934, o wa ni Victoria State Legislature. Nigba ti o se, o wo federal House of Representative. O di Attorney General ile Australia ni aarin 1935 si 1939. Leyin igba ti J. A. Lyons ku ni Menzies wa di olootu Australia. O fi ori oye sile funraare ni 1966.