Abu
Ori sonso oke Aravalli ti o wa ni Rajasthan ni ile India. O ga to ese bata 5650 (5650 ft). Ibi mimo ni Abu je fun awon ti o n si esin Jain