Youssouf Saleh Abbas (ojoibi c. 1953[1]) je oloselu ara Tsad to je Alakoso Agba ile Tsad lati April 2008 de March 2010. Teletele o ti je onimoran diplomati ati asoju fun Aare Idriss Déby.

Youssouf Saleh Abbas
Prime Minister of Chad
In office
15 April 2008 – 5 March 2010
ÀàrẹIdriss Déby
AsíwájúDelwa Kassiré Koumakoye
Arọ́pòEmmanuel Nadingar
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí1953 (ọmọ ọdún 71–72)
Abéché, French Equatorial Africa (now Chad)
  1. "Curriculum vitae du Premier Ministre du Tchad", Chadian government website, April 24, 2008 (Faransé).