Roger David Kornberg (ojoibi (1947-04-24)Oṣù Kẹrin 24, 1947) je ara Amerika onimo kemistri-elemin ati ojogbon oro-emin onidimule ni Ile-Eko Iwosan Yunifasiti Stanford. O gba Ebun Nobel ninu Kemistri ni 2006.

Roger David Kornberg
Roger David Kornberg
Ìbí24 Oṣù Kẹrin 1947 (1947-04-24) (ọmọ ọdún 77)
St. Louis, Missouri, United States
IbùgbéUnited States
Ọmọ orílẹ̀-èdèUnited States
PápáStructural biology
Ilé-ẹ̀kọ́Stanford University,
Harvard Medical School
Ibi ẹ̀kọ́Harvard University (undergraduate),
Stanford University (PhD)
Ó gbajúmọ̀ fúnTransmission of genetic information from DNA to RNA
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́síNobel Prize in Chemistry (2006),
Louisa Gross Horwitz Prize (2006),
Gairdner Foundation International Award (2000)