Austríà

(Àtúnjúwe láti Austria)

Austríà (Gbígbọ́i /ˈɒustriə/ tabi /ˈɔːstriə/; [ˈøːstəˌʁaɪç]  ( listen)), lonibise bi Orileominira ile Austria (German: Republik Österreich), je orile-ede atimo ile to ni awon eniyan bi egbegberun 8.8[2] to wa ni Aringbongan Yuropu. O ni bode mo Orileominira Tseki ati Jemani ni ariawa, Slofakia ati Hungari ni ilaorun, Slofenia ati Italia ni gusu, ati Switsalandi ati Likstenstein ni iwoorun. Gbogbo agbegbe ile Austríà je 83,855 square kilometres (32,377 sq mi) be sini ojuojo ibe je onitutu ati alpini. Ori ile Austríà je oloke gan nitori pe awon Alpi po nibe; 32% ibe nikan ni won wa ni abe 500 metres (1,640 ft), be sin oke re togajulo je 3,798 metres (12,461 feet).[6] Opo awon iyeolubugbe unso ede Jemani,[7] to tun je ede onibise orile-ede ohun.[8] Awon ede ibile onibise miran tun ni ede Kroatia, Hungari ati Slofenia.[6]

Orílẹ̀òmìnira ilẹ̀ Austríà
Republic of Austria

[Republik Österreich] error: {{lang}}: text has italic markup (help)
Orin ìyìn: [Land der Berge, Land am Strome] error: {{lang}}: text has italic markup (help)  (German)
Land of Mountains, Land by the River

Ibùdó ilẹ̀  Austríà  (dark green) – on the European continent  (green & dark grey) – in the European Union  (green)  —  [Legend]
Ibùdó ilẹ̀  Austríà  (dark green)

– on the European continent  (green & dark grey)
– in the European Union  (green)  —  [Legend]

Olùìlú
àti ìlú tótóbijùlọ
Vienna
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaGerman
Lílò regional languagesSlovene, Croatian, and Hungarian
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn
(2001)
91.1% Austrians,
8.9% foreigners -
4% former Yugoslavs,
1.6% Turks,
2.4% others and unspecified[1]
Orúkọ aráàlúAustrian
ÌjọbaFederal Parliamentary republic
• Ààrẹ
Alexander Van der Bellen
Karl Nehammer (ÖVP)
Wolfgang Sobotka (ÖVP)
Independence
• Austrian State Treaty in force
27 July 1955 (Duchy: 1156, Austrian Empire: 1804, First Austrian Republic: 1918–1938, Second Republic since 1945)
Ìtóbi
• Total
83,855 km2 (32,377 sq mi) (115th)
• Omi (%)
1.7
Alábùgbé
• 2020 estimate
8,935,112[2] (93rd)
• 2021 census
8,932,664
• Ìdìmọ́ra
106/km2 (274.5/sq mi) (78th)
GDP (PPP)2018 estimate
• Total
$461.432 billion[3]
• Per capita
$51,936[3]
GDP (nominal)2019 estimate
• Total
$446.315 billion[3]
• Per capita
$50,277[3]
Gini (2020)27 [4]
Error: Invalid Gini value
HDI (18) 0.922[5]
Error: Invalid HDI value · 18th
OwónínáEuro () ² (EUR)
Ibi àkókòUTC+01 (CET)
• Ìgbà oru (DST)
UTC+02 (CEST)
Ojúọ̀nà ọkọ́ọ̀tún
Àmì tẹlifóònù43
ISO 3166 codeAT
Internet TLD.at ³
  1. Slovene, Croatian, Hungarian are officially recognised regional languages and Austrian Sign Language is a protected minority language throughout the country.
  2. Euro since 1 Jan 1999 virtual, since 1 Jan 2002 real currency; before: Austrian Schilling.
  3. The .eu domain is also used, as it is shared with other European Union member states.

Austríà loni ni ibere re lati igba iran-oba Habsburg gegebi ara Obaluaye Romu Mimoy ti Orile-ede awon Ara Jemani; Austria di ikan ninu awon alagbara ninla ile Yuropu. Ni 1867, Ileobaluaye Austria je sisodi Austria-Hungary.

Obaluaye awon iran Habsburg (Austro-Hungarian) daru ni 1918 leyin opin Ogun Agbaye 1k, nigba Austria lo Austria Ara Jemani bi oruko („Deutschösterreich”, todi „Österreich”) lati ba se isokan po mo Jemani sugbon Adehun Saint Germain lodi si eyi. Igba Oselu Austria Akoko je didasile ni 1919. Ni igba Anschluss 1938, Austríà je bibolori latowo Jemani awon Nasi.[9] Eyi je be titi di opin Ogun Agbaye 2k ni 1945, leyin ti Jemani awon Nasi je bibori ogun latowo awon Ore eyi lo da oselu pada si Austríà. Ni 1955, Adehun Orile-ede Ara Austria satun-dasile Austria gegebi orile-ede alaselorile, lati fopin si ibolori. Ni odun yi kanna, Ileasofin Austria da Ifilole Aisojusaju to filole pe Igba Oselu Austria Keji yio di alaisojusaju titi lailai.

Loni, Austríà je oseluarailu asoju onileasofin to ni awon ipinle mesan.[6][10] Oluilu ati ilu re totobijulo, pelu iyeolubugbe to ju egbegberun 1.6, ni Vienna.[6][11] Austríà je ikan ninu awon orile-ede to lolajulo lagbaye, pelu IO oloruko ti enikookan to je $43,723 (idiye 2010). Orile-ede ohun ti sedagbasoke ona igbe giga, be sini ni 2010 o je onipo 25k lagbaye fun Atoka Idagbasoke Omoniyan re. Austríà ti je omo egbe Awon Orile-ede Asokan lati 1955,[12] o sora po mo Isokan Ara Yuropu ni 1995,[6] be sini o je ikan larin awon ti won da OECD sile.[13] Austríà tun fowobowe Ifenuko Schengen ni 1995,[14] o si gba owonina Yuropu, euro, ni 1999.



  1. World Factbook (3 August 2010). "Austria". CIA. Archived from the original on 10 June 2009. Retrieved 14 August 2010. 
  2. 2.0 2.1 "Bevölkerung zu Quartalsbeginn seit 2002 nach Bundesland". Statistik Austria. 4 Nov 2017. Retrieved 4 Dec 2017. 
  3. 3.0 3.1 3.2 3.3 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named imf2
  4. "Gini coefficient of equivalised disposable income – EU-SILC survey". ec.europa.eu. Eurostat. Retrieved 9 August 2021. 
  5. Human Development Report 2020 The Next Frontier: Human Development and the Anthropocene. United Nations Development Programme. 15 December 2020. pp. 343–346. ISBN 978-92-1-126442-5. http://hdr.undp.org/sites/default/files/hdr2020.pdf. Retrieved 16 December 2020. 
  6. 6.0 6.1 6.2 6.3 6.4 "The World Factbook – Austria". Central Intelligence Agency. 14 May 2009. Archived from the original on 10 June 2009. Retrieved 31 May 2009. 
  7. "Die Bevölkerung nach Umgangssprache, Staatsangehörigkeit und Geburtsland" (PDF). Statistik Austria. Retrieved 17 November 2010. 
  8. "Austria". Encyclopædia Britannica. Encyclopædia Britannica Online. 31 May 2009. Retrieved 31 May 2009. 
  9. "Anschluss". Encyclopædia Britannica. Encyclopædia Britannica Online. 24 September 2009. Retrieved 31 May 2009. 
  10. Lonnie Johnson 17
  11. "Probezählung 2006 – Bevölkerungszahl 31.10.2006" (PDF). Statistik Austria (in German). 31 October 2006. Retrieved 27 May 2009. 
  12. Jelavich 267
  13. "Austria About". OECD. Retrieved 20 May 2009. 
  14. "Austria Joins Schengen". Migration News. May 1995. Retrieved 30 May 2009.